YORUBA WORLD NEWS

YORUBA WORLD NEWS 🌍📰

Kaabo si Yoruba World News, ile iroyin ori ayelujara ti o n mu awon iroyin to gbona julo, pataki ati awon alaye to n sele wa fun yin ni ede Yoruba.

A n bo iroyin Nigeria, Yoruba land, Africa ati agbaye, pelu awon oro oselu, awujo, idanilaraya, asa Yoruba, idaraya ati awon isele to n fa ifojusi gbogbo eniyan.

Idi wa ni lati mu iroyin tuntun ati alaye pataki wa si awon oluwo wa ni ona to rorun lati ye ati lati tele.

Subscribe si Yoruba World News ki o si tan notification 🔔 lati ma padanu awon iroyin tuntun wa.

YORUBA WORLD NEWS — IROYIN LATI ILE ATI AYE 🌍