E SEUN BI E SEN BAWA FI IFE WO AWON IROYIN WA, E JOWO E RANWALOWO LATI MA BAWA PIN AWON IROYIN WA KAAKIRI. E SE ADUPE O.
KINDLY LIKE, COMMENT, AND SUBSCRIBE. https://youtu.be/FK8qROnEjCU
Oga agba ile ifowo pamo ni orile-ede Naijiria (Godwin Emefiele) ti so oro jade wipe ki gbogbo ile ifowopamo ni orile-ede Naijiria maa gba owo aloku lo titi di osu kejila odun 2023, ki won si maa koo jade pelu tuntun.
ILE EJO TO GA JU, "SUPREME COURT" L'OJORU NI WON TI SUN IGBEJO LA TI FI TAKO IJOBA APAPO, LORI IGBESE DIDA OWO NAIRA TI WON MU AYIPADA BA DURO NI NAIJIRIA, LATI ILE IFOWOPAMO AGBA ILE WA CBN, TI IJOBA IPINLE KADUNA, KOGI, ATI ZAMFARA PE LATI MA NA AWON OWO TI TELE NA LO, NI NAIJIRIA. SI OJO KEJILE LOGUN , OSUN KEJI, ODUN YI.
Alamojuto fun ile ise ọlọpa nilu Abuja, CP Sadiq Abubakar ti so fun oga ọlọpa ni naijiria IGP Usman Alkali Baba, wipe ki won o gba'se lowo insp Musa Audu to gbe ibon AK-47 re fun pasito ijo, House on the Rock, Abuja, Uche Aigbe ni ojo Sunday.
Iroyin Feli-feli Online Tv
Òwe Yorùbá
1 year ago | [YT] | 6
View 0 replies
Iroyin Feli-feli Online Tv
E SEUN BI E SEN BAWA FI IFE WO AWON IROYIN WA, E JOWO E RANWALOWO LATI MA BAWA PIN AWON IROYIN WA KAAKIRI. E SE ADUPE O.
KINDLY LIKE, COMMENT, AND SUBSCRIBE.
https://youtu.be/FK8qROnEjCU
3 years ago (edited) | [YT] | 7
View 0 replies
Iroyin Feli-feli Online Tv
Peter Obi ti de ile-ejo fun idajo ikehin lori igbejo ejo kotemilorun ti esi idibo Aare ti odun yi.
3 years ago | [YT] | 6
View 0 replies
Iroyin Feli-feli Online Tv
TINUBU SO WIPE OBI ATI KWANKWASO LO PIN IBO ATIKU, NI ILE-EJO TRIBUNAL.
https://youtu.be/QyDUIgPPvts
#news #politics #yoruba #nigeria
3 years ago | [YT] | 2
View 0 replies
Iroyin Feli-feli Online Tv
Oga agba ile ifowo pamo ni orile-ede Naijiria (Godwin Emefiele) ti so oro jade wipe ki gbogbo ile ifowopamo ni orile-ede Naijiria maa gba owo aloku lo titi di osu kejila odun 2023, ki won si maa koo jade pelu tuntun.
3 years ago | [YT] | 6
View 0 replies
Iroyin Feli-feli Online Tv
Apapo esi idibo Are ni ipinle Ogun....
APC jawe olubori ninu idibo Aare ni ipinle Ogun.
#2023ELECTION
3 years ago | [YT] | 5
View 0 replies
Iroyin Feli-feli Online Tv
Apapo esi idibo Are ni ipinle Oyo....
APC jawe olubori ninu idibo Aare ni ipinle Oyo.
#2023ELECTION
3 years ago (edited) | [YT] | 7
View 0 replies
Iroyin Feli-feli Online Tv
ILE EJO TO GA JU, "SUPREME COURT" L'OJORU NI WON TI SUN IGBEJO LA TI FI TAKO IJOBA APAPO, LORI IGBESE DIDA OWO NAIRA TI WON MU AYIPADA BA DURO NI NAIJIRIA, LATI ILE IFOWOPAMO AGBA ILE WA CBN, TI IJOBA IPINLE KADUNA, KOGI, ATI ZAMFARA PE LATI MA NA AWON OWO TI TELE NA LO, NI NAIJIRIA. SI OJO KEJILE LOGUN , OSUN KEJI, ODUN YI.
3 years ago | [YT] | 10
View 0 replies
Iroyin Feli-feli Online Tv
Ajo NDLEA ti fi owo ofin mu Olori ile ijosin kan fun esun gbigbe ogun oloro.
3 years ago | [YT] | 2
View 0 replies
Iroyin Feli-feli Online Tv
Alamojuto fun ile ise ọlọpa nilu Abuja, CP Sadiq Abubakar ti so fun oga ọlọpa ni naijiria IGP Usman Alkali Baba, wipe ki won o gba'se lowo insp Musa Audu to gbe ibon AK-47 re fun pasito ijo, House on the Rock, Abuja, Uche Aigbe ni ojo Sunday.
3 years ago | [YT] | 3
View 0 replies
Load more